- Country
- Nigeria
- Language
- English
- Released
- 2025-04-17
- Runtime
- 3m 12s
- Viewers
- 2,374
Storyline
Stream/Download Barrystar Vol. 1 - https://barryjhay.lnk.to/BarrystarVol.1 Listen to SMSG - https://barryjhay.lnk.to/SMSG Lyrics: [Intro: Chief Dr. Sikiru Ayinde Barrister (MFR) & Barry Jhay] Ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro Ọrọ mi d'akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu Koda, ko ṣe China t'ọn gbe ti n jẹ wọn Ẹni j'alangba n tutu, a kó warapa Oh-ah, oh-ah-ah-ah Yeah, ay-ya-ay, ah-ah, ah Oh-wa, oh, wa-wa-wa (Nobody's perfect) [Verse 1] Yea, k'iku ma-ma pa awọn to gbe mi s'ori bi gele Ki ibanujẹ jina si wa rere, tefe-tefe K'iku ma p'ọta mi, ko le r'iran wo (O ri mo fa to n jo, and they no fit hold me, different effect, ah) Ki'ku ma p'ọta mi, ko le r'iran wo (Mo ṣi n m'ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese Lapo, ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na) [Pre-Chorus] If I see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one Motivation gan ti n pa'yan, wahala nikan kọ o Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ) [Chorus] See me, see God o, abi emi naa kọ Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah Ṣe you dey see level o? Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yеah, tẹti mọ ọ, ye [Verse 2] Ye, as I dey find wеtin I go chop, ooh-iy Make I no jam wetin go chop me Olúwa lo gbe (Yea-yea), lo gbe mi s'oke Emi ko le ṣ'ai ṣope [Chorus] See me, see God o, abi emi naa kọ Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?) Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (Yeah) Yeah, o l'oju ọmọ to damọ [Pre-Chorus] If I see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one Motivation gan ti n pa'yan, wahala nikan kọ o Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ) [Chorus] See me, see God o, abi emi naa kọ Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?) Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo














![Christina Shusho - Thamani Ya Wokovu (Official Audio) SMS [Skiza 7119932] to 811](/api/img?w=400&u=https%3A%2F%2Fpbcdn.aoneroom.com%2Fimage%2F2025%2F07%2F08%2F4a349a30dbc859694879c1f2d6e9a493.jpg)



![Michael Bublé - Have Yourself A Merry Little Christmas [Official HD]](/api/img?w=400&u=https%3A%2F%2Fpbcdn.aoneroom.com%2Fimage%2F2024%2F10%2F21%2F67d767366b656206e397180c1948526c.jpg)
